22
Mar
Off

Speech to text

Àfọ́ di kíkọ sílẹ̀

Noun

  • Bí kò sí Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́, kò sí àfọ́-di-kíkọ-sílẹ̀. Àpèkọ ni ìmọ̀ ọgbọ́n-àmúṣe arannilọ́wọ́ fún ẹni tí kíkọ ọ̀rọ̀ sílẹ̀ ṣòro fún. Àpèkọ náà ni à ń pè ní “àfọ́ di kíkọ-sílẹ̀,” “ohùn di ọ̀rọ̀ kíkọ sílẹ̀” tàbí “ìdáfọ̀mọ̀”.

If there is no Machine Learning, there is no Speech-to-Text. Dictation is an assistive technology tool that can help with writing issues. Dictation is sometimes called “speech-to-text,” “voice-to-text” or “speech recognition” technology. 

Tags: , , , , , , , , , ,