Artificial Intelligence (AI)

Òye tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) Òye tí kì í ṣe ti ẹ̀dá [ọmọ ènìyàn]
Òye Tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) jẹ́ ẹ̀ka ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ ayárabíàṣá tí ó ń ṣe ìdàgbàsókè àwọn ẹ̀rọ oní-òye, tí ó ń ronú àti ṣiṣẹ́ bí ẹ̀dá ọmọ-ènìyàn. Fún àpẹẹrẹ ìdáfọ̀mọ̀, wíwà ojútùú síṣòro, tòun ti kíkRead More…

Direct Current (DC)

Ìṣàn Tààrà (DC) Ìṣàn tààrà (DC) ni irúfẹ́ ìṣàn iná mànàmáná tí ó máa ń ṣàn tààrà sí ìhà kan ṣoṣo. DC ní igun méjì tí ó dúró fún + àti -, fún àpẹẹrẹ àwọn òkúta agbagbára-iná-sára gbogbo ni ó jẹ́ ìṣàn tààrà. Kí á má fi ikú wé oorun, agbára iná DC kì í ṣe ẹgbẹ́ra pẹ̀lú ti AC.
Direct current (DC) is Read More…