Clipboard

Pátákó-ìdìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìdìmú
  Pátákó kékeré tí ó ní iga ìdìmú lórí, tí ó ṣe é mú ìwé (tákàdá) dání tí ó sì ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìkọ̀wé A small board with a spring clip at the top, used for holding papers and providing support for writing.  
Ìtumọ̀ Mìíràn
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìRead More…

Navigate

Daríkiri Ọ̀rọ̀-Ìṣe (Verb)
Da+orí+kiri [Daríkiri] Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè daríkiri/lọ kiri ètò náà bí wọ́n ṣe ń tẹ iṣẹ́ ìwádìí wọn jáde Graduate students navigate the system as they publish research.
 
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìda+orí+kiri [Ìdaríkiri] Ìdaríkiri ọkọ̀ lójú pópó Navigation of vehicle on the highway.
 
Read More…