19
Jan
Off
Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú Noun Kíkọ-èdè-iṣẹ́ àìrímú [Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú] Adébáyọ̀ ń kọ́ nípa ìmọ̀ kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Adébáyọ̀ is learning about programming. Kọ èdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Write a program.    
19
Jan
Off
Akọdùàṣírí ẹ̀rọ Noun Akọ+odù+àṣírí ẹ̀rọ [Akọdùàṣírí ẹ̀rọ] Akọ+èdè+iṣẹ́ àìrímú [Akèdè iṣẹ́ àìrímú] Akọdùàṣírí ẹ̀rọ/akèdè iṣẹ́ àìrímú mẹ́jọ ló kọ odù yẹn  It is eight developers/programmers that wrote the code.  
19
Jan
Off
Ìfiṣàpẹẹrẹ-orí-ẹ̀rọ Noun Ìfiṣàpẹẹrẹ-orí-ẹ̀rọ Ìfiṣàpẹẹrẹ-orí-ẹ̀rọ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi kọ́ ọkọ̀-òfuurufú wíwà The student used simulation to learn aircraft piloting.
19
Jan
Off
Ọkọ̀ Noun Ọkọ̀ Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ mẹ́wàá ni aṣojú wa ń gùn Our representative drives ten cars (vehicle). Ọkọ̀ òfuurufú Boeing 737 já Boeing 737 crashed. Ọkọ̀ ojú-omi ré ní Èkó Ship/boat/canoe sink in Lagos. [caption id="attachment_2291" align="aligncenter" width="300"] Ọkọ̀ ojú-omi[/caption] Ọkọ̀ akérò kan ní ìjàmbá ní orí afárá-kẹ́ta erékùṣù Èkó One commercial vehicle had an accident on the Lagos third-mainland bridge. Ọkọ̀ abẹ́-ibúomi Submarine. Ìjọba ìpínlẹ̀...