Battery
Òkúta-agbanására Noun
(Òkúta agba + iná + sára) Òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ mi ti wú. My phone’s battery has swollen. Read More…
Òkúta-agbanására Noun
(Òkúta agba + iná + sára) Òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ mi ti wú. My phone’s battery has swollen. Read More…
Ihò-ìtẹ̀bọ̀ Noun Ti okùn afagbárainásẹ́rọ ìbánisọ̀rọ̀ bọ ihò-ìtẹ̀bọ̀ (sọ́kẹ́ẹ̀tì) Insert the phone charger into the socket Ihò-ìtẹ̀bọ̀ gbiná The socket exploded Read More…
Afagbárainásẹ́rọ Noun
(A+fi+agbára+iná+sí+ẹ̀rọ) Fi afagbárainásẹ́rọ mi gbéná sínú òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká rẹ Use my charger to charge the battery of your mobile phone Read More…
Pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́ Noun
Ìsàlẹ̀ ojú-ẹ̀rọ niPátákó-gbọọrọ-iṣẹ́náà máa ń wà tí ó ní Bẹ̀rẹ̀, àwọn ààmì Pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́,…
The Taskbar is at the bottom of the desktop and contains the Start, Taskbar icons,… Read More…
Ìpa ẹ̀rọ Noun
(Ìpa ẹ̀rọ) Lọ sí pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́, wo ọwọ́ òsì, te Bẹ̀rẹ̀ kí o ṣira tẹ ìpa ẹ̀rọ. Go to the task-bar, on the left hand side, click on Start and click shut down.
Pa ẹ̀rọ Verb Adéwálé pa ẹ̀rọ nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down when he finished Adéwálé pa ẹ̀rọ ayárabíàṣá nígbà tRead More…
Àwòrán-olóhùn Noun Fi àwòrán-olóhùn mọ́ ọ̀rọ̀ náà. Attach the video with the text Read More…
Ìpín Noun Ṣíra tẹ àtẹ̀ìpàṣẹ ìpín Click on the share button Pín Noun Pín àwòrán-olóhùn náà. Share the video. Read More…
Ààtò Noun Tún ààtò ibi-ìkọ̀kọ̀ orí Facebook rẹ̀ tò. Reset the privacy setting on your Facebook. Read More…
Ìfipamọ́ Noun
Iṣẹ́ tí mo ṣe ń ṣe ìfipamọ́ sí inú àpò-àkápọ̀ àwòrán.
The work I did is saving inside the picture folder Fi-pamọ́ Verb Fipamọ́ sí inú àpò-àkápọ̀ àwòrán. Save it in the picture folder. Ṣíra tẹ àtẹ̀ìpàṣẹ fipamọ́. Click on save button. Read More…
Àpò-àkápọ̀ Noun
Inú àpò-àkápọ̀ àwòrán ni mo fipamọ́ sí.
I saved it inside the picture folder. Read More…