Clipboard

Pátákó-ìdìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìdìmú
  Pátákó kékeré tí ó ní iga ìdìmú lórí, tí ó ṣe é mú ìwé (tákàdá) dání tí ó sì ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìkọ̀wé A small board with a spring clip at the top, used for holding papers and providing support for writing.  
Ìtumọ̀ Mìíràn
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìRead More…

Navigate

Daríkiri Ọ̀rọ̀-Ìṣe (Verb)
Da+orí+kiri [Daríkiri] Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè daríkiri/lọ kiri ètò náà bí wọ́n ṣe ń tẹ iṣẹ́ ìwádìí wọn jáde Graduate students navigate the system as they publish research.
 
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìda+orí+kiri [Ìdaríkiri] Ìdaríkiri ọkọ̀ lójú pópó Navigation of vehicle on the highway.
 
Read More…

Programming

Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú Noun
Kíkọ-èdè-iṣẹ́ àìrímú [Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú] Adébáyọ̀ ń kọ́ nípa ìmọ̀ kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Adébáyọ̀ is learning about programming. Kọ èdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Write a program.
 
  Read More…

Simulation

Ìfiṣàpẹẹrẹ-orí-ẹ̀rọ Noun
Ìfiṣàpẹẹrẹ-orí-ẹ̀rọ Ìfiṣàpẹẹrẹ-orí-ẹ̀rọ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi kọ́ ọkọ̀-òfuurufú wíwà The student used simulation to learn aircraft piloting. Read More…

Vehicle

Ọkọ̀ Noun
Ọkọ̀ Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ mẹ́wàá ni aṣojú wa ń gùn Our representative drives ten cars (vehicle). Ọkọ̀ òfuurufú Boeing 737 já Boeing 737 crashed. Ọkọ̀ ojú-omi ré ní Èkó Ship/boat/canoe sink in Lagos. Ọkọ̀ akérò kan ní ìjàmbá ní orí afárá-kẹ́ta erékùṣù Èkó One commercial vehicle Read More…