17
Mar
Off
Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán máa ń yí àwòrán padà sí ẹ̀dà àìrídìmú fún lílò lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá. . Scanner converts images into digital versions for use on a computer.      
17
Mar
Off
Ìfẹ̀rọ ayárabíàṣá gbéṣẹ́ àìrídìmú sórí àwọsánmà Láyé òde òní, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn àti iléeṣẹ́ ni ó ń lo ìlànà ìfẹ̀rọ ayárabíàṣá gbéṣẹ́ àìrídìmú sórí àwọsánmà pa iṣẹ́ wọn mọ́. In today's world, many people and companies are using the e-cloud process to store their works.
17
Mar
Off
Àká iṣẹ́ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Àká iṣẹ́ ni ibi ìpamọ́ ohun gbogbo tí à ń ṣe ní orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá. The hard disk is the store house of all activities that we perform on the computer.  
17
Mar
Off
Ìṣàsopọ̀ tinú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ìṣàsopọ̀ ti + inú Èyí ni ìṣàsopọ̀ tinú tàbí ìṣàsopọ̀ ti agbègbè kan ṣoṣo tí ó wà fún àwọn ènìyàn kan ṣoṣo. Ìyẹn ìṣàsopọ̀ abẹ́lẹ̀ tí ó jẹ́ wípé àwọn ènìyàn díẹ̀ ni ó ní àyè sí ìlò rẹ̀. This is Intra-network or local area network for just one entity. That is a private network that only a few people has...
17
Mar
Off
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélétantẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ a + yára + bí + àṣá    À + gbé + lé + itan + tẹ̀ Pa ojú ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélétantẹ̀ yẹn dé kí o wá. Close that laptop (computer) and come.
17
Mar
Off
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélẹ̀tẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Brian ni ó ṣe ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélẹ̀tẹ̀ tuntun tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rà. Brian made the new desktop computer that I just bought.  
17
Mar
Off
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb) Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò [caption id="attachment_2344" align="aligncenter" width="225"]  [/caption] (more…)
17
Mar
Off
Ẹnu-àbáwọlé ṣiṣẹ́ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Orí ibùdó-ìtakùn ẹnu-àbáwọlé ṣiṣẹ́ ilé ìwé wọn ni mo ti rí i. It is on their school web portal that I (saw) found it.