Scanner
Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán máa ń yí àwòrán padà sí ẹ̀dà àìrídìmú fún lílò lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá.
. Scanner converts images into digital versions for use on a computer.
Read More…
Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán máa ń yí àwòrán padà sí ẹ̀dà àìrídìmú fún lílò lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá.
. Scanner converts images into digital versions for use on a computer.
Read More…
Ìfẹ̀rọ ayárabíàṣá gbéṣẹ́ àìrídìmú sórí àwọsánmà Láyé òde òní, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn àti iléeṣẹ́ ni ó ń lo ìlànà ìfẹ̀rọ ayárabíàṣá gbéṣẹ́ àìrídìmú sórí àwọsánmà pa iṣẹ́ wọn mọ́. In today’s world, many people and companies are using the e-cloud process to store their works. Read More…
Àká iṣẹ́ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Àká iṣẹ́ ni ibi ìpamọ́ ohun gbogbo tí à ń ṣe ní orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá. The hard disk is the store house of all activities that we perform on the computer. Read More…
Ìṣàsopọ̀ tinú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìṣàsopọ̀ ti + inú Èyí ni ìṣàsopọ̀ tinú tàbí ìṣàsopọ̀ ti agbègbè kan ṣoṣo tí ó wà fún àwọn ènìyàn kan ṣoṣo. Ìyẹn ìṣàsopọ̀ abẹ́lẹ̀ tí ó jẹ́ wípé àwọn ènìyàn díẹ̀ ni ó ní àyè sí ìlò rẹ̀. This is Intra-network or local area network for just one entity. That isRead More…
Ìṣàsopọ̀ ti Agbègbè kan Read More…
Ìṣàsopọ̀ Agbègbè t’ó Gbòòrò Read More…
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélétantẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ẹ̀rọ a + yára + bí + àṣá À + gbé + lé + itan + tẹ̀ Pa ojú ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélétantẹ̀ yẹn dé kí o wá. Close that laptop (computer) and come. Read More…
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélẹ̀tẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Brian ni ó ṣe ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélẹ̀tẹ̀ tuntun tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rà. Brian made the new desktop computer that I just bought. Read More…
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb)
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò (more…)Read More…
Ẹnu-àbáwọlé ṣiṣẹ́ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Orí ibùdó-ìtakùn ẹnu-àbáwọlé ṣiṣẹ́ ilé ìwé wọn ni mo ti rí i. It is on their school web portal that I (saw) found it. Read More…