Subscribe
Sanwósí Verb
San + owó + sí Sanwósí orí ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká rẹ. Subscribe on your mobile phone.
Fi + ọwọ́ + sí Fọwọ́sí ìgbàròyìn tuntun Subscribe to get the latest news Read More…
Sanwósí Verb
San + owó + sí Sanwósí orí ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká rẹ. Subscribe on your mobile phone.
Fi + ọwọ́ + sí Fọwọ́sí ìgbàròyìn tuntun Subscribe to get the latest news Read More…
Owóòlò-ayélujára orí ẹ̀rọ-alágbèéká Noun
Owó + ìlò + ayélujára orí ẹ̀rọ-alágbèéká Owóòlò-ayélujára orí ẹ̀rọ-alágbèéká ni àwọn àkópọ̀ ohun orí ayélujára tí a gbé sórí ẹ̀rọ bí i ẹ̀rọ-alágbèéká àti ẹ̀rọ-ọlọ́pọ́n tí ó la orí ìsopọ̀ àìlokùn ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́. Mobile data is Internet contentRead More…
Ìsanwósí Noun
Ìsan + owó + sí (to pay to have access to something) Mo ṣe ìsanwósí DSTV. I did a DSTV subscription.
Ìfi + orúkọ + sílẹ̀ (to put down one’s name/register for a purpose; for access to something) Jẹ́ kí a lọ ṣe ìforúkọsílẹ̀ fún owó-ìlò-ayélujára Let us go for subscription for internet data. Read More…
Fifún Verb
Fi + fún (give out) Nígbà tí Ọpẹ́yẹmí kọ orúkọ sílẹ̀ tán, ó ṣíra tẹ fifun. After Ọpẹ́yẹmí has entered her name/subscribed, she clicked on submit. Fi ìbéèrè fún Google. Submit a query to Google. Read More…
Ipò Noun Èyí ni atọ́ka sí ipò tí ẹ̀rọ tàbí ònṣàmúlò wà, fún àpẹẹrẹ; ipò ìjáde; ipò àìṣedéédé ẹ̀rọ… This is a pointer to the state (condition) of a device or user, for example; exit status, device malfunctioning status…
Read More…
Ìráàyèwẹ̀rọfiṣẹ́ẹ̀jẹ́ránṣẹ́ Verb
Ìrí-àyè-wọ-ẹ̀rọ-fi-iṣẹ́-ìjẹ́-ránṣẹ́ Èdè ìperí ìráàyèwẹ̀rọfiṣẹ́ẹ̀jẹ́ránṣẹ́ ni dídíbọ́n tàbí títakóró wọ inú ẹ̀rọ, inú iṣẹ́ àìrídìmú, awo àrídìmú tàbí ẹ̀rọ ayárabíàṣá ẹlòmìíràn. The term spoof refers to hacking or deception thaRead More…