Cinematograph
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb)
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò (more…)Read More…
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb)
Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò (more…)Read More…
Ẹnu-àbáwọlé ṣiṣẹ́ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Orí ibùdó-ìtakùn ẹnu-àbáwọlé ṣiṣẹ́ ilé ìwé wọn ni mo ti rí i. It is on their school web portal that I (saw) found it. Read More…
Alákòóso Ẹ̀tọ́ Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá
Read More…
Odiìsanwó Noun
Gbogbo ibùdó ìtakùn àgbáyé kọ́ ni ènìyàn lè mú àkóónú rẹ̀ lò ní ọ̀fẹ́, àwọn kan ń gba owó àsanlò kí òǹṣàmúlò ó tó lè rí àyè sí ohun tí wọ́n bá fẹ́. Odi ìsanwó (ògiri ìsanwó) ni ìlànà ìpààlà tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí ìdílọ́wọ́ tí kò jẹ́ kí ènìyàn rí àyè sí ìwífún orí ibùdó-ìtakRead More…
Títúmọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Bí a bá ń sọ nípa èdè iṣẹ́ àìrídìmú, a kò le è yọ títúmọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú tí í ṣe aàyàn ògbufọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú kan sí èdè òmíràn. When we talk about programming language, we cannot throw aside porting which is the translation of one programming (protocoRead More…
Àfihàn onísùnún Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Àfihàn onísùnún (oní + ìsún) Olùkọ́ wa fi àfihàn onísùnún ṣe àgbékalẹ̀ bí a ṣe ń pa aṣọ láró nípasẹ̀ lílo ìsún àwòrán mẹ́wàá. Our instructor used slide show to make a presentation of how clothes are dyed using ten picture slides. Read More…
Oríta ìbáṣepọ̀ òǹṣàmúlò Oríta tí àwọn nǹkan tàbí ọmọ ènìyàn àti nǹkan (bí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá) ti máa ń pàdé ni interface. Torí ìdí èyí, oríta ìbáṣepọ̀ òǹṣàmúlò (ìyẹn UI ní Gẹ̀ẹ́sì) ni àyè tí ìbáṣepọ̀ láàárín ẹ̀dá ọmọ ènìyàn àti ẹ̀rọ ti máa ń wáyé. The point or place where things or huRead More…
Àjúmọ̀ṣe Ìkànnì ìkéde Ọ̀rọ̀ àpọ́nlé (Adjective) Àjúmọ̀ṣe Ìkànnì ìkéde ni àwọn ohunèlò orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá tí ó máa ń f’èsì sí ohunkóhun tí ònṣàmúlò bá ṣe nípasẹ̀ ìgbéjáde àwọn àkóónú ọ̀rọ̀, àwòrán tí ó ń ṣípò, àwòrándààyè, àwòrán-olóhùn, ohùn, àti àwọn ohun ìṣeré oláwòránRead More…
Ìfihàn ní gbangba Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìfihàn ní gbangba Iléeṣẹ́ náà ṣe ìfihàn-ní-gbangba láti polówó ọjà rẹ̀ tuntun The company did a demonstration to promote her new product Ẹgbẹ́ akọrin tàkàsúfèé àṣẹ̀ṣẹ̀ dá ń ṣe ìfihàn ní gbangba fún ìgbáradì ìkáhùnsílẹ̀ àwo orin wọn The newly formed hip-hop group is doing a Read More…